Smiley face

Linda Ikeji dapewo bi fiimu agbelewo

Linda Ikeji, asaaju ti a ba n so nipa oniroyin ayelukara nile Naijiria ti di apewo bi iran bayii. Ninu abala iwe iroyin Thisday ti n se agbejade oge ti won pe ni Thisday Style ni won ti se afihan awon foto re eleyii ti TY Bello ya.

Ka ma paro, Linda re wa lobirin.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment