Smiley face

Mo si ma n ba iyawo mi lo aso re- Pastor E. A. Adeboye

Adari ijo irapada agbaye, RCCG, Pastor E. A Adeboye ti so wi pe, oun si ma n ba iyawo re lo aso ti won gba a laye lati sebi.

Alaye yii ni ojise Olorun yii n se nigba ti n salaye ojuse asaaju gege bi olusin. O ni eni ti won ba pe ni asaaju gbodo ni emi lati si awon eniyan yala ni oju taye tabi ni koro.


Eyin okunrin ti e ki ran iyawo yin lowo ninu ile, se e ti ri bi awon okunrin gidi ti n se?

Mo palu fun gbogbo yin, e ma bami nibe.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment