Smiley face

"Omo mi ko jale ri ooo" Iya Dammy Krane ti pariwo soke

Awon Yoruba lonii, ko ni buruburu ko ma ku enikan moni. Sugbon eni ti yoo ku la o mo. Iya Dammy Krane, Elizabeth Oluwakemi ti kede wi pe, omo oun ki i jale. A ti wi pe, ise ota ni gbogbo ohun to n sele."O si dami loju eleyii wi pe ti Oluwa ni yoo pada se." Iya Dammy Krane

Dammy Krane to je okan lara awon omo olorin ile Naijiria ni won mu fun esun ole, jibiti ati makaruru nipa lilo oruko oloruko lati sise buruku.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment