Smiley face

Won ti dana sun okan lara awon omo eyin baddo ti n da Ikorodu laamu.

Ohun a ti gbo bayii ni wi pe, okan lara awon omo eyin baddo ti won sise ibi ni agbegbe Ikorodu to wa niluu Eko ni awon ara ilu ti dana sun bayii.
Oro naa tile fa wahala laaarin awon ara ilu ati awon olopaa ti won fe mu afura si naa lo.
Sugbon awon ara Ikorodu yari dele wi pe awon yoo se idajo fun afurasi ti won mu naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment