Emi ba isele naa rin eleyii ti a ko le so iye won bayii. Sugbon aimoye lo fara pa pelu dukia to sofo.
Awon eniyan jona ninu ijamba ina to waye ni Felele lonii
Ijamba oko waye lonii ni ikorita felele to wa ni Lokoja, ni oju ona marose Kogi si Abuja, nibi yii ni oko epo NNPC ti gbe rolu oko akero ti n rin irin-ajo.



0 comments:
Post a Comment