Sugbon bi Mr Johnson ko tile yanu soro, gbogbo eniyan lo mo wi pe atorin atilu Ayuba yato laaarin awon onifuji ile yii.
Yato si eleyii, eniyan jeeje ni Oba Bonsue, eleyii to fi soro lati gbo oruko re nibi won ba ti n ja lagbo onifuji.
Ju gbogbo re lo, Ayuba ni awon oniroyin ise oge gba wi pe, o rewa ju lo lawujo awon olorin fuji.
Kini ero yin nipa Adewale Ayuba?
0 comments:
Post a Comment