Smiley face

@Funmilola Iyanda: Iba oosa funfun ajiki

Oloju ologbon to jomiloju. Nitori ki i se gbogbo ologbon ni won ran aye lowo.

Ki i se gbogbo eniyan nla lo se pataki.

Sugbon ti Funmiola Iyanda yato gedegede ni mo se fori bale f'oosa funfun oninu ire.

Igba odun, odun kan ni. Ase

#HappyBirthday

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment