Ojo keji ni yii ti awon gomina oke oya ti n se ipade po.
Oni ni ojo keji ti awon gomina ni apa oke oya ti n pejopo fun apero eleyii ti yoo mu itesiwaju ba apa oke oya ile Naijiria. Lara afojusun won lati ri eto aabo, eko, idagbasoke amaye-rorun, eto oro aje ati irepo alaafia.




0 comments:
Post a Comment