Smiley face

Ebora Owu ti n ko iwe mii: Obasanjo tun fe da "gobe" sile

Okan ninu awon ololufee aare ana, Oloye Olusegun Obasanjo, Ogbeni Emeka Oparah, ti tu asiri wi pe, Ebora ilu Owu ti setan lati ju akanse iwe mi i jade eleyii ti yoo mi ilu titi.

Sebi gbogbo wa lati mo Alaremu pelu awon gbankogbi iwe re, eleyii to ma n mu awuyewuye dani.

Oparah, to je okan lara awon agba osise ile ise Airtel, ko lati so akole iwe naa, sugbon o so wi pe, iwe naa yoo lekenka.

"I can confirm that OBJ at 80 (officially) is doing at least one book. I won't mention the topic but it will shake the world. And that's why I love the stubborn, crafty old man-perhaps the greatest Nigerian alive-who at his age still pushes his staff to their breaking points." - Emeka Operah


Alaye foto: Ogbeni Emeka Oparah ati OBJ

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment