Smiley face

Fela ti darapo mo Obatala, Sango Ogun ati awon oosa akunlebo to ku.

Ere omode ko, bi won se n bo awon oosa akunlebo bi Obatala, Sango, Ogun bee naa ni awon fi ori bale fun ere Fele Anikulapo bayii lojubo ile adulawo, Afrika Shrine, to wa nIkeja nipinle Eko.

Opolopo lo gba wi pe, abami eda looto ni omo Funmilayo je, eleyii ti ko si enikeni to tako aba naa.

Gege bi itan isedale se fi ye wa, awon oosa akunlebo bi Obatala, Sango, Oya, Esu, Ogun ni won ti fi igba kan je eniyan lati wa jise Olodumare lode aye.

Bee gele ni Fela je ojise Olodumare nigba aye re, eleyii lo fi soro lati ri eni bi re mo lode aye.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment