Sugbon sa, awon ololufe Ajela ko gba fun olorin fuji naa lati wa lai pede orin fun won.
Eleyii ni a fi ri Igwe fuji bo se sariya ni awon ibi kan ni ilu Amerika. Sugbon bayii, omo Aluko ti kede wi pe, asiko ti to lati pada si Naija.
Adura wa ni wi pe, ki Oluwa ba wa mu de layo ati alaafia.
0 comments:
Post a Comment