Smiley face

"Ọfẹ́ ni Béèli" - @YomiShogunle

Ayajo oni ti awon eniyan se igbelaruge fun ede Yoruba lori ero Twitter, igbakeji komisanna awon olopaa, ogbeni Abayomi Shogunle, ti lo anfaani naa lati kede lede Yoruba wi pe, ofe ni beeli ni ago olopaa kari gbogbo ile Naijiria. Alaye maanu ni yii nisale

"Ọfẹ́ ni Béèli ni ago ọlọpa orilẹ-ede Nigeria 🇳🇬.
Ti wọn ba beere fun owo, epe @PoliceNG_PCRRU.
Jọwọ efi eyi han ẹnikan loni."

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment