Smiley face

Ipolongo #TweetInYoruba ti n lo lowo bayii lori Twitter

Kaakiri agbaye ni awon Yoruba ti ya ojo oni soto lati so ede Yoruba pombele lori ero Twitter. E le darapo mo won nipa lilo #TweetInYoruba. Bakan naa ni e le tele emi naa loju opo @OlayemiOniroyin.

Yoruba Dun pupo!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment