Smiley face

Kayode @Ogundamisi naa ti darapo mo #TweetInYoruba

Agbaoje onise iroyin, alariwisi oro ti n lo lowo, eni to fi ilu Oba se ibujokoo, Ogbeni Kayode Ogundamisi naa ti dara po mo #TweetInYoruba.

O je idunnu awon awon ololufe re gege bi okunrin naa se se afihan ara gege bi ojulowo omo Yooba gidi.

Ikede ti Ogbeni Ogundamisi fi sita ni yii:
'Eni ni ojo Eti, ojo kejidinlogbon odun 2017, ojo ti awa omo Yoruba, omo Karo O ji ire, ojo ifi gbe àṣà Yorùbá lárugẹ 🇳🇬 #TweetInYoruba."

E le tele Ogundamisi loju opo @ogundamisi lori Twitter. @OlayemiOniroyin ni temi.

Yoruba Dun gan-an

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment