Smiley face

Ise tuntun Hakeem Effect bani leru gidi

Hakeem Onilogbo ti gbogbo eniyan mo si Hakeem Effect to je asarologe tun ti safihan akotun ise re lati oko ere tiata.

Ise asaraloge ti rekoja ka kun atike funfun si osere loju nikan, ise naa ti debi ka seda ohun ti ko si laye tabi ohun ti ko si larowoto.

Lara iru e ni oku eniyan to ja jalajala ti Hakeem tun dogbon re yii.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment