Sugbon gege bi iforowero pelu Olayemi Oniroyin, osere naa je ko ye wa wi pe, oun ko fi ise tiata sile nigba kankan.
Gege bi alaye re, o ni lotitoo ni wi pe, oun fa seyin ni awon akoko kan sugbon bayii, awon ololufe oun yoo tun ma je igba dun awada lorisirisi.
0 comments:
Post a Comment