Smiley face

Omo King Wasiu Ayinde Marshal n mura eto igbeyawo tuntun

Okan ninu awon omo King Wasiu Ayinde Marshal, Sulauliman Yomade Anifowose ti n mura bayii lati se igbeyawo alarinrin pelu ololufe re.

Bi o tile je wi pe won ti mu ojo igbeyawo, sugbon won ko ti fi ran lati kede re faye. Eleyii ti mo se gan an ofofo ni, Oloun ma si je o ko ba mi.

Lafikun, ilu Eko ati Ijebu Ode, ilu Oba Sikiru Adetona, ni igbeyawo naa yoo ti gbe waye.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment