Smiley face

Omidan obirin to duro fun aadota (50) odun ti pada se igbeyawo

50-year-old lady 

Arabirin Omolayo Oyeyemi Oyewole, eni aadota odun, 50, ti se igbeyawo fun igba akoko pelu ololufe re, Pastor Mike Gbade Adetutu. 


Ohun ti a gbo ni wi pe, opo ni Pasito Mike ko to di wi pe o se igbeyawo pelu Omolayo. Inu ijo Irapada ti awon mejeeji jon lo to wa niluu Abuja, Redeemed Christian Church of God (RCCG), Fountain of Living Water Parish, Tudun Wada, Abuja,  naa ni igbeyawo won ti waye ninu osu keja odun yii.

Olorun oba lo ni deede. A gbadura wi pe gbogbo ere igbayawo ni Olorun yoo fi ke won. Amin
 
50-year-old lady 
50-year-old lady 
50-year-old lady
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment