Smiley face

Won ti fi igo gun oju oniroyin nibi to ti n foju wa iroyin gidi

Senator Shehu Sani, okan ninu awon senato ti won soju ilu Kaduna, lo kede wi pe, awon omo aye ti jego loju oniroyin ti oruko re n je Lawal Mohammed nibi ipade kan pelu awon oniroyin ni Kaduna

"Journalist Lawal Mohammed stabbed by sponsored armed thugs 4 covering our Press conference in Kaduna" - Senator Shehu Sani

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment