Smiley face

Won ti gbe ade tuntun le aya Femi Fani-Kayode [@realFFK] lori

Oloye Femi Fani-Kayode ti ranse ikini ku oriire si aya re, Precious, eni to jawe olubori gege bi orekelewa obirin to lenu loro ju lo ni ile Naijiria. Ohun ti minisita fun eto irina ofurufu nigba kan so ni yii:

"I congratulate my beautiful wife
for winning the Most Influential Beauty Queen in Nigeria Award.U make me proud baby! I love u." - FFK

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment