Smiley face

Awon janduku APC se wa nijamba ni Wuse Abuja- @AdeyanjuDeji

Ogbeni Deji Adeyanju, okan ninu awon ti won pe fun ifiposile aare Muhamadu Buhari tabi ki aare pada senu ise re lo ti kede bayii wi pe, awon janduku kan ti won je ti egbe APC ti kolu okan lara awon omo egbe won.

Oun kan naa lo se afihan foto eni ti won se ni ijamba yii.

Awon egbe yii #OurMumuDonDo #ResignorResume lo dide leyin ti Aare Buhari ti lo opolopo ojo ni ilu London latari aisan eleyii to pamo si ara ilu.

Bakan naa, ni ana yii lagbo wi pe, awon kan ba oko Charley Boy je eni ti oun naa je okan ninu awon egbe naa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment