Smiley face

Awon omo soja Naijiria ti lo posi wa lori oro Boko Haram.

Awon omo ologun ile Naijiria ti lo tunramu pelu bi won se lo posi wa lati koju iko omo alakatakiti esin, Boko Haram, ti won da apa oke oya laamu.

Ti e ko ba gbagbe, ni ana ni awon omo Boko Haram tun sose ni ipinle Adamawa leyin ti opo awon omo Naija sebi opin ti de ba won.

Sugbon sa, ti ina ko ba tan laso eje ki i tan leekanna ni awon omo ologun ile yii fi oro naa se pelu bi won se lo sigun wa lakotun pelu awon oko ogun ti n yona lenu bi Sango olukoso oko Oya.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment