Smiley face

Oko ajagbe akeru ti lo ka baba iberin mole lojo isomoloruko: Ise owo gomina ni

Gomina ipinle Sokoto, Aminu Waziri Tambuwal, ti fi oko ajagbe ko ounje ati eru omo tuntun fun okunrin agbe-alaroje kan ti iyawo re bi iberin ni ipinle re.

Okunrin agbe yii ti oruko re n je Lawwali Maishinkafa ni won tun fun ni #500, 000 gege bi iranlowo fun ise agbe ti n se.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment