Smiley face

ADÉBÁYỌ̀ FÁLÉTÍ NÍ OJÚ ÀWỌN ÈNÌYÀN.

Eto ojo kin-in-ni fun ayeye ikeyin fun baba Alagba Adebayo Mosobalaje Ajibade Akande Faleti ni Gbongan Trenchard ninu UI. Lara awon ti won kopa ninu eto naa ni baba Alagba Olatunbosun Oladapo, Aare Diipo Gbenro, Alagba Tunde Kelani, baba Yemi Elebuibon, Ojogbon Duro Adeleke, Egbe Onkowe Yoruba, Egbe Akomolede, Egbe Osere Yoruba, Egbe ANA abbl

Ero pọ̀, ètò pọ̀, kò sì tíì tàn-án.
Orisun: Oluko Ede Yoruba
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment