Smiley face

Idi ti Yinka Quadri ati Eniola Badmus fi je 6&7 ni yii

Bi o tilẹ je wi pe awon mejeeji ti se opolopo fiimi to larinrin ti won si gbajumo. Sugbon awon ololufe ise sinima to yanranti ko le gbagbe ipa ti ọkan ko ninu Jenifa ati akitiyan ẹlẹẹkeji ninu fiimu kan ti n jẹ 150 Million. 

Eniola Badmu

Ojo ayọ ni asiko yii jẹ fun Eniola Badmus ti awon kan tun mo si "Gbogbo bis girl" ati Alhaji Yinka Quadri ti awon kan mọ si "Kura" pelu bi won se le lọdun lonii lọjọ keje ati kefa osun kesan odun yii.

Yinka Quadri
Ọjọ keje osu kesan-an odun 1977 ni won bi Eniola Badmus nigba ti won bi Alhaji Yinka Quadri lọjọ kefa osun kesan-an odun 1958.

A fi asiko yii ki awon meejei ku ojo ibi, igba odun odun kan ni


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment