Smiley face

Sangbafọ! Gbajumo oserebirin ile Naijiria ti sin ọmọ rẹ kan soso

Ibanujẹ nla ni ki obi fi ọwọ re sin omo rẹ tobi. Pelu ẹdun okan nla ni mo fi n kede fun yii wi pe, Eucharia Anunobi, oserebirin elede geesi, ti sin omo re kan soso to ni laye lorun, Raymond Ekwu, bayii. 

Adura mi ni wi pe ki Oluwa tun arabirin naa ninu. Ibanuje ko ni ya ile wa. Amin

 

 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment