Smiley face

Ogede omoge meje ni mo n je, Floyd Mayweaher lo so bee

Image result for Floyd Mayweather with ladies
"Awon omoge meje ni mo n je ogede agbagba won papo leekan naa." Floyd Mayweaher, afeseku bi ojo lo so bee. Ninu alaye re to ti n so bi o se n gbe igbe aye re, o ni ki eniyan ni obirin kan dabi eni ti ko ni rara ni. Meje ni awon orebirin mi, a si jo ma n jade lati gbadun ara wa papo ni.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment