Smiley face

Rogbodiyan Arewa ati Biafra: Awon Hausa ti sun oja awon Yibo ni Kaduna


Igbo market 
Gbajugbaja oja awon omo Yibo to wa ni ipinle Kaduna ni awon omo Hausa ti dana sun bayii. Awon dukia to je aimoye milionu ni won ti sofo patapata. Pupo ninu awon omo Yibo naa ni won salo nigba ti awon omo gambari ya de.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment