Smiley face

Epe buruku: Tí wón bá sanwo fun e láti gbeja Buhari, posi ni wà fọwọ́ yẹn ra lodun 2018" - Ta ló ń ṣepe gan-an?

Ọkàn nínú àwọn olólùfẹ́ ẹgbẹ́ PDP, Demola Olanrewaju, tí fepe ranse si àwọn ololufe Buhari ti won ma takoo ni joojumo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment