Smiley face

Ìdí pàtàkì tí ẹ̀bùn ọdún fi ṣe pàtàkì

Ìkéde pàtàkì fún àwọn ènìyàn pàtàkì tí wọ́n rí ÌDÍ pàtàkì tí ìkéde yìí fi jẹ́ pàtàkì.

Àwọn ènìyàn pàtàkì tí rí ìdí pàtàkì láti  fún ara wọn ní nǹkan ọdún pàtàkì. sugbọn títí di àkókò yìí, àwọn ènìyàn mi, àwọn ènìyàn pàtàkì, wọ́n ko ti ri ìdí pàtàkì láti fún mi ní ẹ̀bùn pàtàkì fọ́dún.

Ìdí pàtàkì tí mo fi fi ìdí pàtàkì yìí hàn kò ju kí ẹ le ri ìdí pàtàkì tí mo fi yẹ láti gba ẹ̀bùn pàtàkì.

Jugbogbo rẹ lọ, Àǹfààní sì wá fún ẹnikẹ́ni láti fi ẹ̀bùn ọdún ranse si mi.

E ku ipalemọ ọdún aláyọ̀

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment