Smiley face

ABDUL FATAI MOSOBALAJE AJEIGBE tí lọ sinmi: Gbogbo ayé ń sedaro leyin akoni

" AWAYE  AI-KU  O  SI "    =     E bami d'aro  Baba wa,  ABDUL  FATAI  MOSOBALAJE   AJEIGBE, 'Baba  Egbe - Ogba'. "OLU-ODE"  ti ile ijoba ibile IGANNA (Oke  Ogun)  ni Ipinle Oyo Alaafin, ni tile  t'oko.

Won lo sibi Agba a re, lojo Jimoh, ojo kokan-din-logun osu SEERE t'a wa ninu re yi. Olodumare bawa te won s'afefe rere.      =  =  =  =  =  "

- Dókítà Adeleke Gbola Ademola

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment