Smiley face

Ohun tí Obasanjo gbàgbé kò fi sínú lẹta rẹ -Reuben Abati

"Obasanjo gbìyànjú nípa bó se menuba kudiẹkudiẹ isejoba Buhari. Ṣùgbọ́n ohun kan tó gbàgbé láti kó sínú leta rẹ ni, titorọ aforiji lọ́wọ́ àwọn ọmọ Nàìjíríà nípa bó ṣe mu wọn ko sínú  panpe Buhari"-  Reuben Abati, oludamoran nípa ìròyìn fún Aare àná, Goodluck Janathan, tí fèsì padà sí leta Ebora ìlú Òwu

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment