Smiley face

Diezani Alison-Madueke yọ wa rata ọbẹ̀ lọja

Àwọn ọmọ Adamọ tí ganni Diezani Alison-Madueke níbi to ti yọ wá rata loja nílùú London.
Arábìnrin yìí ni minisita epo robi nígbà kan eléyìí tí wọn lo jí obitibiti owó salọ lábẹ́ isejoba Goodluck Janathan

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment