Smiley face

Lasun Ray náà yọ ayọ̀ ọjọ́ ìbí lónìí #HappyBirthday

Bí gbogbo àwọn ènìyàn ṣe ń kí Muyiwa Ademola Authentic kú oriire ọjọ́ ìbí, bẹẹ naa ni wọn kì Lasun Ray Eyiwumi kú ayọ̀ ọdún tuntun ọjọ ibí tiẹ̀ náà tó kọ layo lónìí 26/01/18. #HappyBirthday

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment