Smiley face

Omo ọdún mokanla (11yrs) tí lóyún oṣù márùn-ún nílùú China

Ọmọbìnrin ọmọ ọdún mokanla, omo ile ìwé ìlú China lọ tí lóyún oṣù márùn-ún báyìí látàrí ibasun láti ọwọ ogbeni Liu Baoming (50yrs) to je aṣọ́bodè iléèwé tí ọmọ náà ń lọ.

Ọmọbìnrin tí wọn pé ní Lele tí ara rẹ kò ya ní ìyá rẹ gbé lo sì osibitu, ibè ni àṣírí isele naa si ti gbé tú wí pé oyun tí dúró sí Lele lára.

Ọkùnrin asobode iléèwé Lele sì tí jewo wí pé ilé akọpati kan lẹgbẹ ile ìwé wọn ní òun ti lọ ma n kona bo ọmọ náà lábẹ́.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment