Smiley face

OMO ỌDÚN MOKANLA (11YRS) TÍ LÓYÚN OṢÙ MÁRÙN-ÚN NÍLÙÚ CHINA (2)

Ṣáájú, a ti gbé ìròyìn ọmọbìnrin ẹni ọdún mokanla tí bàbá ẹni àádọ́ta (50) fún lóyún nílùú China.

Àwọn òbí ọmọ náà tí ń gbìyànjú láti ṣe oyún ọmọ náà eléyìí tí bàbá aṣọ́bodè ilé ìwé wọn fún un.

Gege bí itopinpin ilé ìṣe ìròyìn ìlú China ṣe gbé jáde, wọn ní Lele ọmọ ọdún mokanla tí wọn fún lóyún ni ọkàn nínú àwọn ẹbí rẹ tẹ́lẹ̀ tí fipá bá lopọ nígbà tó wà lomo ọdún mẹsan an sáájú kí wọn to fún lóyún nígbà to pé ọdún mokanla.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment