Smiley face

Ènìyàn pàtàkì bí Lara Olubo: Ọbabirin Sorosoro Agbaye

Bí ènìyàn bá semi loore mo ti ṣèlérí wí pé mi ò ní gbàgbé.

Ọjọ́ tí mo n wà ènìyàn kan ṣoṣo láti dúró fún mi. Lara Olubo dúró fún mi lọ́nà mẹ́wàá.

Lọjọ tí ilẹkun mú mi lọ́wọ́ , Lara Olubo ni dókítà to wo mi san.

Bí ènìyàn semi loore mo ti ṣèlérí wí pé mi ò ní gbàgbé.

Kii se gbogbo ẹni tó ga lọ fẹ k'ẹlòmíì ga.
Kii se gbogbo olówó lófẹ́ kówó kárí.
Bẹ́ẹ̀ ó lójú ẹni lè soore fun ni lai gbobì àbàtà.

Lara Olubo jọ mi lójú
Ẹni ba ri, ẹ wí fún wọn wí pé Olayemi Oniroyin mọ wọn lèèyàn pàtàkì.

Lara Olubo... Ọbabìnrin Sorosoro Agbaye... Iba!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment