Smiley face

Ohun tí awon ọmọ ológun Nàìjíríà gba lọ́wọ́ Boko Haram ni yìí

Lọjọ Isegun to kọjá, àwọn ọmọ ológun Naijiria yawo ibùdó àwọn ọmọ Boko Haram ni Ipinle Borno won sì ṣe wọn bí ọsẹ ti ń soju.

Àwọn ọmọ Boko Haram náà ko lè dúró níbi tí ibon tí ń rò kíkankíkan.

Àwọn ohun ìjà tí wọn ba ni ibùdó wọn ní yìí leyin ikolu to wáyé náà.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment