Smiley face

Ìdí tí àwọn ènìyàn fi pa Alfa Salami lórúkọ dà ní yìí

Oríṣiríṣi ogun, wàhálà àti ìdojúkọ ni ọmọ ẹ̀dá ń kọjú nílé ayé. Àwọn kan ségun, àwọn kan sì bogun lọ.

Ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run nìkan ló lè gbé ẹ̀dá ro àti àdúrà.

Lára àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tí ẹ̀dá ń kọjú láyé, eléyìí to bá mi lọ́kàn jẹ julo ni ìròyìn nípa ogbontarigi agbaboolu orileede Nàìjíríà eléyìí tí ayé gbójú lọ́wọ́ rẹ, tí wọn sì padà sọ dẹni tí ń tọrọ jẹ.

Ẹ lé ká ìròyìn agbaboolu náà [NIBI]

Ó ṣe pàtàkì kí ènìyàn sunmọ àwọn ènìyàn Ọlọ́run fún àdúrà àti ona àbáyọ láti borí ìṣòro ẹ̀dá láyé.

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé àwọn onirọ tí pọ bí erupe ilẹ̀, sibesibe àwọn olotitọ ẹ̀dá sí wa.

Lára wọn ni Alfa Salami, ẹni tí àwọn ènìyàn pa lórúkọ dá sí Sheu Àṣeyọrí látàrí àìmọye ènìyàn to tí rí ìwòsàn àti itusile nípasẹ̀ rẹ. 

Yàtò sì gbigba àdúrà nípa ìsòro kí ìṣòro tó lè kóju ẹ̀dá, Allahu tún fún Sheu Àṣeyọrí ṣe nípa àìsàn ara ojú tó ti fọ, stroke, àìrí ọmọ bí àti bẹẹ bẹẹ lọ.

E lé kan sì wọn lórí àwọn number yii:
07065865035
08113280526

Address 13, Sele Òkè Ila, Ado Ekiti, Ekiti State, Nigeria.




Nínú Iroyin míì tó tun jáde :

Ogbontarigi agbaboolu Naijiria tidi afoju onibaara

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment