Smiley face

Vision Classic tí gbogbo ènìyàn ń wá kiri ní yìí

Lori ìkànnì yìí náà láti kéde nígba díẹ̀ sẹ́yìn wí pé, ọkàn nínú àwọn ọmọge Lekki ń wá ọmọkùnrin tó kọrin Bebe Chop My Money.

Ẹ lè ka ìròyìn náà [NIBI]

Ní báyìí àti rí ọmọkùnri náà tí ń jẹ Vision Classic.

Yàtò sì wí pé ó jẹ́ arẹwà ọkùnrin, Ọlọ́run fún lẹ́bùn orin púpọ̀. Bóyá nǹkan tí ọmọge Lekki rí re e to fi ń wá bobo náà kiri.

E lé download orin Vision Classic [NIBI]

Ṣùgbọ́n sá, àwọn ènìyàn tí ń kìlọ̀ fún bobo náà wí pé kò rọra

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment