Smiley face

Ìtàn Olajumoke arẹwà obìnrin (pt2)

OLAJUMOKE PART 2......

Bi Olajumoke se ri okunrin arewa iwin yìí, ó sún mọ́, ó bèrè oruko rẹ.

Bẹẹ ni iwin yi so fun pe ORIOLA ni oruko oun. Jumoke tun bèèrè wí pé se ilu yii naa lo n gbe sugbon Oriola ni rara o ilu odikeji ni mo ti wá.

Jumoke tun beere pe baba ati iya re nko, oriola tun daa lohun pe won wa n'ilu wa ati pe omo olowo ni òun.

O ni agbe nla ni baba oun ati pe baba oun gbajumo ju oba ilu awon lo.

Iya oun je gbajugbaja onisowo koko o si ni omo ise to po jáni rere.

Jumoke tun beere pe ise wo ni Oriola ń se o daa lohun o ni onisowo nla ni ohun àti pé oun a maa sowo kaakiri ilu si ilu ati ileto si ileto.

Inu jumoke dun si ohun to gbo lenu Oriola o si ro ninu ara re pe oun yóò o fe okunrin iwin yi ni tipatipa ati tí patí kúkú.

Ò wa sọ fun Oriola pe se o lè gba lati je ore timotimo oun a ti pé inu oun yio dun ti o ba le ko oun ni ise ọwọ.

Oriola si gba bee, leyin ti won soro tan Oriola ni akoko to mo ti fe maa lo sugbon oju Olajumoke kò gbà á. Nigba tó yá, Jumoke gba fun un lati maa lo...... e maa bawa kalo


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment