Smiley face

Ohun tí ẹ kò mọ nípa Shina Rambo ògbólógbòó ọlọ́ṣà (4)

Shina Rambo, ẹni tó ti di pasito báyìí tí fi ìgbà kan gùn ọmọ tuntun metadinlogbon (27) lọsẹ nínú odo rí.

Bákan náà lọ tí pa ọgọ́rùn-ún ènìyàn rí láti jẹ ahọn wọn gẹ́gẹ́ bí asejẹ agbára .

Yato si eléyìí, ògbólógbòó ọlọ́ṣà yìí tí bá ìyá to bi lọmọ sún rí ní ọ̀nà àti wá agbára.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment