Smiley face

Omoge Lekki n wa Vision Classic to korin Beby Chop my money

Mo n wa Vision Classic to korin Baby Chop My Money


E dakun ran mi lowo oo

A ti ale ana lomoge Lekki yii ko ti je n gbadun o.

O ni ki n ba oun wa bobo kan ti won pe ni Vision Classic to korin ti won pe ni Beby Chop my money. "Mi o mo orin to n so arabirin yii se emi ni manija re ni?" Lo ba tun send orin naa si mi, koda omobirin naa tun se fidio orin naa. O ni dandan mo gbodo ba oun wa bobo naa ri. Iyawo mi tile n binu lale ana wi pe ibo ni mo ti pade awon omo Science Student. Se temi o ba mi bayii.

https://my.notjustok.com/track/download/id/313621

Link orin naa ni yii, eni to ba mo bobo ko saanu mi. Abi, Olorun ma ma je n sise gba ke. 

https://my.notjustok.com/track/download/id/313621

Fidio omo naa wa NIBI


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment