Smiley face

Oyun méjìdínlógún (18) lọ bajẹ lára mi nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ si ni fẹ Gani Adams - Mojisola Adams

"Lónìí, adùn ni ṣùgbọ́n mo ti fi ìgbà kan wá nínú ibanuje ri. Oyún bí méjìdínlógún (18) lọ bajẹ lára mi nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ pelu ọkọ mi, Gani Adams.

Àwọn kan yínmu, wọn ṣe yẹyẹ mi. Wọn ní ọkọ mi ti fi nǹkan ọmọkùnrin rẹ wà agbára wí pé mi o lè lóyún.

Ìgbàgbọ́ mi dúró, ẹni dúró de Olúwa kii pofo. Lẹ́yìn òkùnkùn, imole de. Yẹyẹ mi di ayẹyẹ. Mo padà sabiamọ, mo tún di aya Ààre Ọ̀nà Kakanfo Ilẹ̀ Yorùbá.

Gbogbo àwọn ọrẹ mi tí wọ́n  sá nígbà náà lo ń wù won  báyìí ki wọn jẹ aya Gani Adams."- Erelu Mojisola Adams

(Mummy, ẹ má gba fún wọn kí won gbọkọ yin ó. Àwọn eleriibu sombọdi)

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment