Smiley face

"Ọlọ́run Adeboye fi Ibẹrin pẹgan mi rẹ - Ẹri láti ìjọ RCCG

Ọmọbìnrin to tí ń woju Ọlọ́run fún ọmọ fún àìmọye ọdún padà wá jẹri níwájú Olúwa fún Ibẹrin (ọmọ mẹ́rin lẹẹkan náà).

Ẹri yìí wáyé nínú ìpàdé 2018 Special Holy Ghost Service tí ìjọ RCCG eléyìí tí wọn pé àkòrí rẹ ni Stronger Than Your Enemies pt3. 2/3/2018

A ba ìwọ náà yọ lai pẹ. Àmìn 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment