Smiley face

Ìgbéyàwó láàárín ọmọ gómìnà ipínlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti gomina ìpínlè Kano tí gbéra

Fàájì òpin ọsẹ yii yóò fakiki ni ipinle Kano níbi tí Abolaji Ajimobi, ọmọkùnrin gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo, yóò ti má gbé Fateema Ganduje, ọmọbìnrin gómìnà ipínlẹ̀ Kano, gẹgẹ bí ìyàwó alarede ni ìlànà ẹṣin musulumi.

Àìmọye àwọn bọrọkinni lagbo òṣèlú ni wọn si ti ń sọkalẹ si ipinle Kano báyìí.

Fàájì yẹn má le kú!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment