Smiley face

Kayode Ogundamisi tí ṣe àlàyé àwọn irumole tí ń wọn jẹ dollar lowolowo

"Ìgbà ni gbogbo nǹkan láyé. Ayé ìgbà kan ni Government Ekpemupolo tí inagijẹ rẹ ń jẹ Tompolo, Soboma George, Ateke Tom, Mujahid Dokubo-Asari àbbl.

Àwọn irumole tuntun tí wọn pawó nínú rògbòdìyàn àti ìjínigbẹ́ báyìí ni Abubakar Shekau, Abu Musab al-Barnawi àti àwọn agbódegbà wọn nínú ìjọba" - Káyọ̀dé Ogundamisi

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment