Smiley face

Ọmọ Naija to jẹ Senator ní Italy tí bínú tán o

Ènìyàn dúdú àkọ́kọ́ ti yoo di Senator ní orileede Italy, Ogbeni Tony Iwobi, ti ṣe kilọkilọ fún àwọn ènìyàn tí wọn gba ọna ẹyin wọlé sí orileede náà láti sọra. Nínú ọ̀rọ̀ ọkùnrin tó ti fi ìgbà kan gbé ní Nàìjíríà 🇳🇬 ri, ó ní àkókò yìí tí yàtò sì ìgbà kan. Ẹni ba si fojú ana wọ eégún, onitohun yóò dára rẹ lẹbi. Iwobi ni ilé igbimo asofin Italy yàn gege bí ọkàn lára ìgbìmò alabẹ sekele láti rísí àwọn tí wọn fi ona èrú wọ Italo 🇮🇹

*Maanu yẹn para gidi gan ni fa* 😂

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment