Smiley face

Lẹ́yìn ikú Ishola Oyenusi, ògbólógbòó adigunjale, ohun ti ìwé ìròyìn sọ lodun 1973 ni yii

Gẹ́gẹ́ bí ìwé ìròyìn Daily Times ọdún 1973 ṣe sọ. Lèyín ikú ògbólógbòó adigunjale, Ishola Oyenusi, ọlọ́wọ́ ọtun rẹ, Mighty Joe, pitu méje tí òde ń pa nínú igbó.

Might Joe tilẹ so wí pé kò sí babanlaku ọlọ́pàá to lè rí òun mu nítorí òun náà loogun to dájú lọ́wọ́.

Ọdún 1973 ni wọn padà feyin Might Joe tagbe, tí wọn sì rọ̀jọ̀ ìbọn sì i láyà.

Olóòtú ìwé ìróyin ọdún náà ti lẹ̀ jẹ kò yẹ wá wí pé, náírà mẹ́wàá ni Mighty Joe padà jí tí ọwọ fi tẹ.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment