Smiley face

Sharpville Massacre: Ìṣẹ̀lẹ̀ burúkú to ṣẹlẹ̀ ni South Africa lọ́dún 1960

Ayajọ ojo oni, March 21, lodun 1960  ni àwọn òyìnbó ajẹ́lẹ̀ ṣekú pa àwọn ènìyàn dúdú ni orileede South Africa.

Won ṣe àwọn ènìyàn dúdú sakasaka, wọn fi àdá bẹ àwọn kan lórí, wọn gùn ẹlẹ́mìí lọ́bẹ ni kún, nígbà tí wọn ti wọn bajinatu rán àwọn kan lọ sorun ni orileede náà.

Gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ṣe sọ, àwọn ènìyàn tí wọn pa to metadinlaadorin nígbà tí àìmọye farapa kọjá sísọ. Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ni wọn pé akole rẹ ni Sharpville Massacre.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment